Jẹnẹsisi 47:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Josẹfu pèsè ohun jíjẹ fún baba ati àwọn arakunrin rẹ̀, ati gbogbo àwọn ìdílé baba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí iye eniyan tí olukuluku wọn ń bọ́.

Jẹnẹsisi 47

Jẹnẹsisi 47:9-13