Jẹnẹsisi 47:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Josẹfu bá fi baba ati àwọn arakunrin rẹ̀ sí ibi tí ó dára jùlọ ní ilẹ̀ Ijipti, ninu ilẹ̀ Ramesesi, gẹ́gẹ́ bí Farao ti pa á láṣẹ.

Jẹnẹsisi 47

Jẹnẹsisi 47:1-12