Jẹnẹsisi 45:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ níláti sọ fún baba mi nípa gbogbo ògo mi ní Ijipti, ati gbogbo ohun tí ẹ ti rí. Ẹ tètè yára mú baba mi wá bá mi níhìn-ín.”

Jẹnẹsisi 45

Jẹnẹsisi 45:7-17