Jẹnẹsisi 45:12 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ̀yin pàápàá fi ojú rí i, Bẹnjamini arakunrin mi náà sì rí i pẹlu pé èmi gan-an ni mò ń ba yín sọ̀rọ̀.

Jẹnẹsisi 45

Jẹnẹsisi 45:2-19