Jẹnẹsisi 43:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Juda dá a lóhùn, ó ní, “Ọkunrin náà kìlọ̀ fún wa gidigidi pé a kò ní fi ojú kan òun láìjẹ́ pé a mú arakunrin wa lọ́wọ́.

Jẹnẹsisi 43

Jẹnẹsisi 43:1-10