Jẹnẹsisi 43:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n jẹ ọkà tí wọ́n rà ní Ijipti tán, baba wọn pè wọ́n, ó ní, “Ẹ tún wá lọ ra oúnjẹ díẹ̀ sí i.”

Jẹnẹsisi 43

Jẹnẹsisi 43:1-6