Jẹnẹsisi 41:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnikẹ́ni kò sì ní mọ̀ pé oúnjẹ ti fi ìgbà kan pọ̀ rí, nítorí ìyàn ńlá tí yóo tẹ̀lé e yóo burú jáì.

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:28-39