Jẹnẹsisi 41:30 BIBELI MIMỌ (BM)

ṣugbọn lẹ́yìn náà ìyàn yóo mú fún ọdún meje, ìyàn náà yóo pọ̀ tóbẹ́ẹ̀ tí ọdún meje tí oúnjẹ pọ̀ yóo di ìgbàgbé ní ilẹ̀ Ijipti, ìyàn náà yóo run ilẹ̀ yìí.

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:27-39