Jẹnẹsisi 41:1-2 BIBELI MIMỌ (BM) Lẹ́yìn ọdún meji gbáko, Farao náà wá lá àlá pé òun dúró létí odò Naili. Ó rí àwọn mààlúù