Jẹnẹsisi 42:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jakọbu gbọ́ pé ọkà wà ní ilẹ̀ Ijipti, ó wí fún àwọn ọmọ rẹ̀ pé, “Kí ni ẹ̀ ń wo ara yín fún?

Jẹnẹsisi 42

Jẹnẹsisi 42:1-8