Jẹnẹsisi 40:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní òru ọjọ́ kan, agbọ́tí ọba ati olórí alásè náà lá àlá kan, àlá tí olukuluku lá sì ní ìtumọ̀ tirẹ̀.

Jẹnẹsisi 40

Jẹnẹsisi 40:2-11