Jẹnẹsisi 40:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Alabojuto ọgbà ẹ̀wọ̀n náà fi wọ́n sábẹ́ àkóso Josẹfu, wọ́n sì wà ní ọgbà ẹ̀wọ̀n náà fún ìgbà díẹ̀.

Jẹnẹsisi 40

Jẹnẹsisi 40:1-8