Jẹnẹsisi 40:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kẹta tíí ṣe ọjọ́ ìbí Farao, ọba se àsè ńlá fún gbogbo àwọn iranṣẹ rẹ̀, ó sì mú agbọ́tí rẹ̀ ati alásè rẹ̀ jáde sí ààrin àwọn iranṣẹ rẹ̀.

Jẹnẹsisi 40

Jẹnẹsisi 40:12-23