Jẹnẹsisi 40:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn ọjọ́ mẹta, Farao ọba yóo yọ ọ́ jáde níhìn-ín, yóo bẹ́ ọ lórí, yóo gbé ọ kọ́ igi, àwọn ẹyẹ yóo sì jẹ ẹran ara rẹ.”

Jẹnẹsisi 40

Jẹnẹsisi 40:14-20