Jẹnẹsisi 40:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ní àkókò kan, agbọ́tí Farao, ọba Ijipti, ati olórí alásè rẹ̀ ṣẹ ọba.

2. Inú bí Farao sí àwọn iranṣẹ rẹ̀ mejeeji yìí,

3. ó sì jù wọ́n sí ọgbà ẹ̀wọ̀n ní ilé olórí àwọn tí wọn ń ṣọ́ ààfin ninu ọgbà ẹ̀wọ̀n tí Josẹfu wà.

Jẹnẹsisi 40