Jẹnẹsisi 39:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Alabojuto ọgbà ẹ̀wọ̀n náà kì í fi nǹkan lé Josẹfu lọ́wọ́ kí ó tún bìkítà fún un mọ́, nítorí pé OLUWA wà pẹlu Josẹfu, ohunkohun tí ó bá ṣe, OLUWA ń jẹ́ kí ó yọrí sí rere.

Jẹnẹsisi 39

Jẹnẹsisi 39:19-23