Jẹnẹsisi 4:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Seti bí ọmọkunrin kan, ó sọ ọ́ ní Enọṣi. Nígbà náà ni àwọn eniyan bẹ̀rẹ̀ sí jọ́sìn ní orúkọ mímọ́ OLUWA.

Jẹnẹsisi 4

Jẹnẹsisi 4:19-26