Jẹnẹsisi 4:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Adamu tún bá aya rẹ̀ lòpọ̀, ó lóyún, ó sì bí ọmọkunrin kan. Ó sọ ọ́ ní Seti, ó ní: “Ọlọrun tún fún mi ní ọmọ mìíràn dípò Abeli tí Kaini pa.”

Jẹnẹsisi 4

Jẹnẹsisi 4:15-26