Jẹnẹsisi 4:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó bí ọmọkunrin mìíràn, ó sọ ọ́ ní Abeli. Iṣẹ́ darandaran ni Abeli ń ṣe, Kaini sì jẹ́ àgbẹ̀.

Jẹnẹsisi 4

Jẹnẹsisi 4:1-10