Jẹnẹsisi 39:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Josẹfu kọ̀, ó wí fún un pé, “Wò ó, níwọ̀n ìgbà tí mo wà lọ́dọ̀ ọ̀gá mi, kò bìkítà fún ohunkohun ninu ilé yìí, ó sì ti fi ohun gbogbo tí ó ní sí ìkáwọ́ mi.

Jẹnẹsisi 39

Jẹnẹsisi 39:2-9