Jẹnẹsisi 39:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn ìgbà díẹ̀, Josẹfu wu aya ọ̀gá rẹ̀, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí rọ̀ ọ́ pé kí ó wá bá òun lòpọ̀.

Jẹnẹsisi 39

Jẹnẹsisi 39:1-9