Jẹnẹsisi 35:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Níbẹ̀ ni Debora, olùtọ́jú Rebeka kú sí, wọ́n sì sin ín sí abẹ́ igi oaku kan ní ìhà gúsù Bẹtẹli, Jakọbu bá sọ ibẹ̀ ní Aloni-bakuti.

Jẹnẹsisi 35

Jẹnẹsisi 35:1-17