Jẹnẹsisi 35:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tẹ́ pẹpẹ kan sibẹ, ó sì sọ ibẹ̀ ní Eli-Bẹtẹli, nítorí pé níbẹ̀ ni Ọlọrun ti farahàn án nígbà tí ó ń sálọ fún arakunrin rẹ̀.

Jẹnẹsisi 35

Jẹnẹsisi 35:4-16