Jẹnẹsisi 35:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Jakọbu pada sọ́dọ̀ Isaaki, baba rẹ̀, ní Mamure, ìlú yìí kan náà ni wọ́n ń pè ní Kiriati Ariba tabi Heburoni, níbi tí Abrahamu ati Isaaki gbé.

Jẹnẹsisi 35

Jẹnẹsisi 35:19-29