Jẹnẹsisi 35:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí Silipa, iranṣẹbinrin Lea bí ni: Gadi ati Aṣeri. Àwọn wọnyi ni àwọn ọmọ tí wọ́n bí fún Jakọbu ní Padani-aramu.

Jẹnẹsisi 35

Jẹnẹsisi 35:21-29