Jẹnẹsisi 34:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kó gbogbo aguntan wọn, gbogbo mààlúù wọn, gbogbo kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ wọn, ati gbogbo ohun tí ó wà nílé ati èyí tí ó wà ninu pápá.

Jẹnẹsisi 34

Jẹnẹsisi 34:26-29