Jẹnẹsisi 34:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Jakọbu wá kó gbogbo ohun ìní àwọn ará ìlú náà nítorí pé wọ́n ba arabinrin wọn jẹ́.

Jẹnẹsisi 34

Jẹnẹsisi 34:23-31