Jẹnẹsisi 33:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó yá, Jakọbu dé sí Ṣekemu ní ilẹ̀ Kenaani ní alaafia, nígbà tí ó ń pada ti Padani-aramu bọ̀ ó pàgọ́ rẹ̀ siwaju ìlú náà.

Jẹnẹsisi 33

Jẹnẹsisi 33:8-19