Jẹnẹsisi 33:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Jakọbu lọ sí Sukotu o kọ́ ilé kan fún ara rẹ̀ ó sì ṣe àtíbàbà fún àwọn ẹran rẹ̀. Nítorí náà ni wọ́n Ṣe ń pe ibẹ̀ ní Sukotu.

Jẹnẹsisi 33

Jẹnẹsisi 33:11-20