Jẹnẹsisi 32:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀rù ba Jakọbu gidigidi, ó sì dààmú, ó bá dá àwọn eniyan tí wọn wà pẹlu rẹ̀ ati agbo mààlúù, ati agbo aguntan ati àwọn ràkúnmí rẹ̀ sí ọ̀nà meji meji.

Jẹnẹsisi 32

Jẹnẹsisi 32:5-14