Jẹnẹsisi 32:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn oníṣẹ́ náà pada wá jábọ̀ fún Jakọbu, wọ́n sọ fún un pé, “A jíṣẹ́ rẹ fún Esau arakunrin rẹ, ó sì ń bọ̀ wá pàdé rẹ pẹlu irinwo (400) ọkunrin.”

Jẹnẹsisi 32

Jẹnẹsisi 32:1-12