Jẹnẹsisi 32:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Bákan náà ni ó kọ́ ekeji ati ẹkẹta ati gbogbo àwọn iranṣẹ tí wọ́n tẹ̀lé àwọn agbo ẹran náà. Ó ní, “Nǹkan kan náà ni kí ẹ máa wí fún Esau, nígbà tí ẹ bá pàdé rẹ̀.

Jẹnẹsisi 32

Jẹnẹsisi 32:17-29