Jẹnẹsisi 32:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí o wí pé, ‘Ti Jakọbu iranṣẹ rẹ ni, wọ́n sì jẹ́ ẹ̀bùn tí ó fi ranṣẹ sí Esau oluwa rẹ̀, òun alára ń bọ̀ lẹ́yìn.’ ”

Jẹnẹsisi 32

Jẹnẹsisi 32:14-19