Jẹnẹsisi 32:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sùn níbẹ̀ ní alẹ́ ọjọ́ náà, ó sì mú ninu ohun ìní rẹ̀ láti fi ṣe ẹ̀bùn fún Esau arakunrin rẹ̀.

Jẹnẹsisi 32

Jẹnẹsisi 32:11-14