Jẹnẹsisi 32:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwọ ni o ṣá sọ fún mi pé, ‘Ire ni n óo ṣe fún ọ, n óo sì sọ àwọn ọmọ rẹ di pupọ bí iyanrìn etí òkun tí ẹnikẹ́ni kò ní lè kà tán.’ ”

Jẹnẹsisi 32

Jẹnẹsisi 32:6-13