Jẹnẹsisi 31:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Rakẹli ni ó kó àwọn ère oriṣa náà, ó dì wọ́n sinu àpò gàárì ràkúnmí, ó sì jókòó lé e mọ́lẹ̀. Labani tú gbogbo inú àgọ́ rẹ̀, ṣugbọn kò rí wọn.

Jẹnẹsisi 31

Jẹnẹsisi 31:24-41