Jẹnẹsisi 31:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Labani bá wá inú àgọ́ Jakọbu, ati ti Lea ati ti àwọn iranṣẹbinrin mejeeji, ṣugbọn kò rí àwọn ère oriṣa rẹ̀. Bí ó ti jáde ninu àgọ́ Lea ni ó lọ sí ti Rakẹli.

Jẹnẹsisi 31

Jẹnẹsisi 31:31-40