Jẹnẹsisi 30:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí àwọn ẹran tí kò lókun ninu tóbẹ́ẹ̀ bá ń gùn, kì í fi àwọn ọ̀pá náà siwaju wọn, báyìí ni àwọn ẹran tí kò lókun ninu di ti Labani, àwọn tí wọ́n lókun ninu sì di ti Jakọbu.

Jẹnẹsisi 30

Jẹnẹsisi 30:35-43