Jẹnẹsisi 30:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ẹran tí ara wọ́n le dáradára láàrin agbo bá ń gùn, Jakọbu a fi àwọn ọ̀pá náà siwaju wọn, kí wọ́n lè máa gùn láàrin wọn.

Jẹnẹsisi 30

Jẹnẹsisi 30:33-43