Jẹnẹsisi 30:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ẹran náà ń gun ara wọn níwájú àwọn ọ̀pá wọnyi, wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí bí ọmọ tí àwọ̀ wọn dàbí adíkálà ati àwọn tí wọ́n ní funfun tóótòòtóó.

Jẹnẹsisi 30

Jẹnẹsisi 30:32-43