Jẹnẹsisi 30:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó to àwọn ọ̀pá wọnyi siwaju àwọn ẹran níbi tí wọ́n ti ń mu omi, nítorí pé, nígbà tí wọ́n bá wá mu omi ni wọ́n máa ń gùn.

Jẹnẹsisi 30

Jẹnẹsisi 30:32-43