Jẹnẹsisi 29:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún lóyún, ó sì tún bí ọkunrin, ó ní, “Ọkọ mi gbọdọ̀ faramọ́ mi wàyí, nítorí pé ó di ọkunrin mẹta tí mo bí fún un”, nítorí náà, ó sọ ọmọ náà ní Lefi.

Jẹnẹsisi 29

Jẹnẹsisi 29:24-35