Jẹnẹsisi 29:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún lóyún, ó tún bí ọkunrin, ó ní, “Nítorí pé OLUWA ti gbọ́ pé wọ́n kórìíra mi ni ó ṣe fún mi ní ọmọ yìí pẹlu.” Ó bá sọ ọ́ ní Simeoni.

Jẹnẹsisi 29

Jẹnẹsisi 29:25-35