Jẹnẹsisi 29:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Jakọbu gbà bẹ́ẹ̀, ó ṣe ọ̀sẹ̀ igbeyawo Lea parí, lẹ́yìn náà Labani fa Rakẹli, ọmọ rẹ̀ fún un.

Jẹnẹsisi 29

Jẹnẹsisi 29:25-31