Jẹnẹsisi 29:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Fara balẹ̀ parí àwọn ètò ọ̀sẹ̀ igbeyawo ti eléyìí, n óo sì fún ọ ní ekeji náà, ṣugbọn o óo tún sìn mí ní ọdún meje sí i.”

Jẹnẹsisi 29

Jẹnẹsisi 29:25-33