Jẹnẹsisi 29:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà Labani sọ fún un pé, “O wá gbọdọ̀ máa sìn mí lásán nítorí pé o jẹ́ ìbátan mi? Sọ fún mi, èló ni o fẹ́ máa gbà?”

Jẹnẹsisi 29

Jẹnẹsisi 29:7-24