Jẹnẹsisi 29:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Labani bá dá a lọ́kàn le, ó ní, “Láìsí àní àní, ẹ̀jẹ̀ kan náà ni wá” Jakọbu sì wà lọ́dọ̀ rẹ̀ fún oṣù kan.

Jẹnẹsisi 29

Jẹnẹsisi 29:9-24