Jẹnẹsisi 27:7 BIBELI MIMỌ (BM)

pé kí ó lọ pa ẹran wá fún òun, kí ó sì se oúnjẹ aládùn kí òun lè jẹ ẹ́, kí òun sì súre fún un níwájú OLUWA kí òun tó kú.

Jẹnẹsisi 27

Jẹnẹsisi 27:6-14