Jẹnẹsisi 27:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Rebeka pe Jakọbu ọmọ rẹ̀, ó sọ fún un, ó ní, “Mo gbọ́ tí baba yín ń bá Esau ẹ̀gbọ́n rẹ sọ̀rọ̀,

Jẹnẹsisi 27

Jẹnẹsisi 27:1-7