Jẹnẹsisi 25:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Iṣimaeli sì ń gbé ilẹ̀ tí ó bẹ̀rẹ̀ láti Hafila títí dé Ṣuri, tí ó wà ní òdìkejì Ijipti, ní apá Asiria. Wọ́n tẹ̀dó sí òdìkejì àwọn eniyan wọn.

Jẹnẹsisi 25

Jẹnẹsisi 25:12-23